Pẹlu orukọ Ọlọhun, gbogbo ẹyin tí Ọlọhun ni, ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba ojiṣẹ Ọlọhun ati awọn ara ile rẹ ati awọn saabe rẹ ati awọn ti wọn ba tẹle e, lẹyin naa. Tira kékeré yii: "Sisa kuro nibi aigbagbọ nínú bibẹ Ọlọhun lọ sí inu Isilaamu" Tira pelebe náà n tì siwaju wa alaye kan fún "bi aigbagbọ nínú bibẹ Ọlọhun ṣe rí" ati awọn iruju rẹ, ati bi aigbagbọ ṣe tako àwọn nǹ kan tí o hàn kedere nínú làákàyè àti àdánidá. Ati pe tira kekere yii nṣe afihan awọn ẹri iṣe afirinlẹ bíbẹ Aṣẹ̀̀dá, mimọ fún Un. Sisa kuro nibi aigbagbọ nínú bibẹ Ọlọhun lọ sí inu Isilaamu ; Dr. Haitham Talaat